Pelumi Deborah – Erujeje ft. Bukola Bekes: A Soul-Stirring Worship Anthem Gospel artist Pelumi Deborah teams up with the iconic Bukola Bekes to deliver a powerful worship ..[read more]
Joe Mettle – Afro Christmas ft. Nana Yaw Ofori-Atta: A Festive Celebration of Joy Renowned Ghanaian gospel artist Joe Mettle has released a heartwarming holiday anthem titled “Afro ..[read more]
Okey Sokay – Talk n Do (Live) ft. Oyel Planet & Hugo David: A Celebration of God’s Faithfulness Okey Sokay, a trailblazer in contemporary gospel music, has ..[read more]
Moses Akoh – Baruch Hashem Adonai: A Song of Worship and Reverence Moses Akoh, a rising voice in contemporary gospel music, delivers a profound and soul-stirring ..[read more]
MOGmusic – No Doubt ft. Kingzkid: A Bold Declaration of Faith Ghanaian gospel artist MOGmusic is back with an electrifying new release, “No Doubt,” featuring the dynamic Kingzkid. Known ..[read more]
Embracing the Power of Faith: Exploring Tope Alabi’s Song “Mo Mope Mi Wa”
In the realm of gospel music, few artists possess the ability to touch the soul and uplift the spirit quite like Tope Alabi. With her powerful vocals and heartfelt lyrics, Alabi has captured the hearts of listeners around the world, offering a message of hope, love, and faith. One of her most inspiring songs, “Mo Mope Mi Wa,” stands as a shining example of her musical prowess and her unwavering devotion to spreading the word of God.
Released as part of her [Yes And Amen] album, “Mo Mope Mi Wa” is a soul-stirring anthem that celebrates the unchanging faithfulness of God. From the moment the first notes resonate, listeners are transported into a
realm of divine presence, where doubt and fear are replaced by unwavering trust and confidence in God’s promises.
What sets “Mo Mope Mi Wa” apart is not just its lyrical depth, but also its musical brilliance. Alabi’s rich vocals, accompanied by powerful instrumentation, create an atmosphere of reverence and awe, drawing listeners into a deeper connection with the divine. With each verse and chorus, the song builds to a crescendo of praise and adoration, culminating in a heartfelt declaration of faith and affirmation.
Oba to ku nitori mi, Oba taa pa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi mo mope mi wa fun o Ada lebi iku, kemi le gba idalare Ano ni pasan, kemi maba jiya Oti kikan tomu, kinmaba jekoro ni Atuto si lara, kemi le deni aponle Ikoro irora toje nitori temi ni
Oba toku nitori mi, Oba taapa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi, mo mope mi wa fun o La layi jebi ese, asi da lebi eshe Isho owo ati ese re Pelu oko egbe re Iya eshe mi ni Ori ogo lofi dade egun fun emi o Emi o mo oun ti moja mo o Tofi se gbogbo iwonyi Mo mope mi wa Fun Oba to seyi fun mi
Oba to ku nitori mi, Oba ta pa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi Odo aguntan to k’eshe mi lo Oloore to gbamila o Ope aanu to po yi, mio riri Mo wa pelu emi imore Oba to di alaini kemi le d’loro Mo mope mi wa fun o Baba
Iwo loje kopari Ise ati Iya to tosi mi Iwo loje ko tan aisan ti aarun ti nba ri Iwo logba kokoro iku Ati isa iboji ti nba wo oo Oba to ra iye fun mi Emi mo mope mi wa o oseee Odo aguntan to ko ese mi lo To somi di omo re Mo mope mi wa fun o
Oba ayeraye to fi itere sile wa jiya fun emi Mo mope mi wa fun oo Owo elese ni ijoba orun Kole daduro omase Mo mope wa fun o Oro ayeraye to deru nitori mi Mo mope mi wa fun o Iya toje lona agbelebu manigbagbe ni mo mon Mo mope mi wa fun o
Oba to laye, to lorun To Wa di alai lara Mo mope mi wa fun o Oobo ogo re kale, owaye wa gbese mi wo ooo Mo mope mi wa fun o Oro ishura ogo iyebiye Lofi fun mi loogun jè Mo mope mi wa fun o Iku E lori igi kafari lofi ra iye fun emi Mo mope mi wa fun o Ori ade ayeraye lofi tegun nitori mi o Mo mope mi wa fun o Emi mo riri ajinde re kemi maba shigbe ni Mo mope mi wa fun o Ore-ofe ti mo rigba lai dinyele loje nmope wa Mo mope mi wa fun o
Oun gbogbo tose tose ose fun emi Momope mi wa fun o Bi mo legberun ahon Ko to yin o olupinl’èshè Momope mi wa fun o Alasepe igba gbo Olurapada ore tooto Momope mi wa fun o Momope mi wa f’eni To femi lati odo inu Momope mi wa fun o Oba to feran mi ju enikeni lo ooo Momope mi wa fun o Ore airi oluto okan mi, mogbope ore de Momope mi wa fun o Ope ni mo wa da oo Ope ni mo wa du lodo oloore mi Momope mi wafun o
Leave a Reply