Maxwell Egheose, the gifted Nigerian gospel artist, offers a sincere and moving tribute with his song, “Thank You.” This track instantly wraps you in an ..[read more]
Tim Godfrey, the electrifying Nigerian gospel music general, along with Fearless Community and the vibrant Ebube, unleash pure exhilaration with “Chimle.” This song instantly ignites ..[read more]
Bishop William Murphy III, born August 2, 1973 in Detroit, Michigan, is a Grammy-nominated gospel artist, pastor, and prolific worship leader based in Atlanta, Georgia. Since launching ..[read more]
mmaOMG (also known as MR Jelenke) is a multi-talented Nigerian gospel minister, songwriter, and live performer leading The OhEmGee Band. Known for viral worship sessions ..[read more]
Embracing the Power of Faith: Exploring Tope Alabi’s Song “Eba Mi Ki”
In the realm of gospel music, few artists possess the ability to touch the soul and uplift the spirit quite like Tope Alabi. With her powerful vocals and heartfelt lyrics, Alabi has captured the hearts of listeners around the world, offering a message of hope, love, and faith. One of her most inspiring songs, “Eba Mi Ki,” stands as a shining example of her musical prowess and her unwavering devotion to spreading the word of God.
Released as part of her [Yes And Amen] album, “Eba Mi Ki” is a soul-stirring anthem that celebrates the unchanging faithfulness of God. From the moment the first notes resonate, listeners are transported into a realm of divine presence, where doubt and fear are replaced by unwavering trust and confidence in God’s promises.
What sets “Eba Mi Ki” apart is not just its lyrical depth, but also its musical brilliance. Alabi’s rich vocals, accompanied by powerful instrumentation, create an atmosphere of reverence and awe, drawing listeners into a deeper connection with the divine. With each verse and chorus, the song builds to a crescendo of praise and adoration, culminating in a heartfelt declaration of faith and affirmation.
Obà tó ṣé mi láàánú o (ọbà tó wò mí sún sún tó ṣe mí láàánú)
verse
Your mercy is what am dwelling into
Since I was in my mother’s womb
Olúbi tó ṣe dá tó fi ẹsẹmi lélẹ’
You have been my shield my shelter and light
Iwó loto mi bó o
Pàánpe ọ’nà àyè koje ko mú mi
Morín lafoni foji kòtò gẹ’gẹ’ rẹ oshomi your bound with me is love
Olùsọ ẹ’mí àti àyè tí mòni
Aké ni agẹ’ ni un ó ròyìn re fara yé ki wọn bá mi kí o
chorus
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú o
verse
Botiwu kò gùn pòóto
Botiwu kí ọ’tá pòóto
Ọlọ’run jẹ’ olódodo o
Bowu ósá kò máa sá
Bowu òkun kò má kùn
Òdodo Ọlọ’run yòò wá títí láìlai
Botiwu kò na jìn tó
Botiwu kò kédá tó
Ọlọ’run jẹ’ olódodo o
Botiwu ké kun pòóto
Botiwu kẹrin pòóto
Òdòdó rẹ Ọlọ’run yíò wa titilia
Òjé olódodo
Òdòdó rẹ ko má lópin
Òjé ọlọ títọ
Kí máa se èké bi ènìyàn o
Ọ’rọ’ tó bá tẹnu re jáde òdòdó ni
O gbé ọ’rọ’ rẹ gaju orúkọ àrà rè lo o
chorus
Ẹ má bá mi ki oo ooo
Ẹ má bá mi ki aa aha
Ọbà tó ṣé mi lóore aaee
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi kí ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore (ọbà tó ṣé mi lóore)
Ẹ má bá mi ki ooo (oo)
Ẹ má bá mi ki Aaaa (aaa)
Obà tó ṣé mi láàánú ó (ọbà tó ṣé mi láàánú)
hook
Kosi ìlà kọjá tio mó Ìjì ń jà lóko Jésù sún òróri
Òjó gbó Lórí Sárà
Pelina ń fi Hannah ṣé rin-rin
Botiwu kó ọjọ’ pe tó
Kénì yàn gbàgbé re to
Lati nu agbo eran
Amu Dafidi kékeré kò wá jó bá Òjé olódodo Òdodo re kò má lópin
Òjé ọlọ títọ koma ise ènìyàn
Kólé gbàgbé láì
Ọ’rọ’ toba tẹnu re jáde
Odoni ogbe ọ’rọ’ rẹ ga ju orúkọ ara rẹ lo
chorusẸ má bá mi ki oo oooẸ má bá mi ki aa ahaỌbà tó ṣé mi lóore aaeeẸ má bá mi ki oooẸ má bá mi ki aaaaObà tó ṣé mi láàánú ó (Ẹ má bá mi kí)Ẹ má bá mi kí ó (Ẹ má bá mi kí)Ẹ má bá mi ki aaaaỌbà tó ṣé mi lóore (ọbà tó ṣé mi lóore)Ẹ má bá mi ki ooo (oo)Ẹ má bá mi ki Aaaa (aaa)Obà tó ṣé mi láàánú ó (ọbà tó ṣé mi láàánú)
Leave a Reply